Nigeria Independent ; Ìfìfẹhàn àwọn èniyàn sí ayájọ Òmìnira Nàìjíríà.

Diẹ re lara awọn aworan awomalelọ ti a ṣalabapade loju opo ayelujara.

Aworan ayajọ Omininra Naijiria

Oríṣun àwòrán, Petra Akinti Onyegbule

Àkọlé àwòrán, Ọjọ́ ìbí 'Aunty' Petra bọ́ sí ìgbàkan náà pẹ̀lú ti Nàìjíríà,
Aworan ayajọ Omininra Naijiria

Oríṣun àwòrán, Kashi Images

Àkọlé àwòrán, Obìnrin yìí fi ìfẹ́ hàn sí Orílẹ̀èdè Nàìjíríà
Aworan ayajọ Omininra Naijiria

Oríṣun àwòrán, Al jazeera

Àkọlé àwòrán, Oniroyin Aljazeera yi naa jọ bi ẹni kọwọ idunnu pẹlu Naijiria latari aṣo to wọ
Aworan ayajọ Omininra Naijiria
Àkọlé àwòrán, Ireke oloyin naa wa ti arakunrin yi n ta lọjọ ominira nilu Kano
Bhari àti ìgbìmọ iṣejọba
Àkọlé àwòrán, Àwọn Olórí orílẹ̀èdè Nàìjíríà ń gé àkàrà òyìnbó ayẹyẹ òmìnira
Ayẹyẹ Ominira
Àkọlé àwòrán, Àwọn aláṣẹ ilẹ̀ Nàìjíríà
Akara fun ominira Naijiria

Oríṣun àwòrán, Facebook

Àkọlé àwòrán, Àkàrà Òyìnbó aláwọ̀ ewé láti ṣàyájọ́ ayẹyẹ òmìnira Nàìjíríà