Àṣìlò òògùn: Ará ìlú sọ oun tó ń sún wọn dé'dí ìwà yí

Asilo oogun

Oríṣun àwòrán, Guardian Nigeria

Awọn oniṣegun oyinbo ti n bẹnu atẹ lu aṣilo oogun lati ọjọ to ti pẹ, ṣugbon awọn ara ilu to ba ikọ BBC sọrọ ni wahala ti oju awọn n ri ti wọn ba lọ ile iwosan lo faa ti awọn fi di ẹni to n ṣi oogun lo.

Àkọlé fídíò, Àṣìlò òògùn: Ará ìlú sọ oun tó ń sún wọn dé'dí ìwà yí

Awọn oniṣegun oyinbo ti n bẹnu atẹ lu aṣilo oogun lati ọjọ to ti pẹ, ṣugbon awọn ara ilu to ba ikọ BBC sọrọ ni wahala ti oju awọn n ri ti wọn ba lọ ile iwosan lo faa ti awọn fi di ẹni to n ṣi oogun lo.

Awọn oniṣegun meji, Dokita Yetunde Adeniyi ati dokita Tope Ojo fesi si ọrọ yii, wọn ni, bo ti lẹ jẹ pe nitootọ ni pe oun ti oju ara ilu n ri lati gba iwosan ni awọn ile iwosan ko rọrun, ọpọlọpọ ewu lo wa nidi aṣilo oogun.

Àkọlé fídíò, Àwọn dọkítà ní bó tilẹ̀ jẹ́ pe àṣìlò òògùn kìí ṣe ẹ̀bi awọn ará ìlú, ó mú ewu púpọ̀ dání

Àwọn iroyin miiran ti é le nifẹ si:

Àkọlé fídíò, 'Ọ̀gá ni mí nínú àwọn ẹlẹ́rìín lágbàáyé'