You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
#Russia2018: Belgium ṣíná fún Japan pẹ̀lú àmì ayò 3-2
Japan náà ń kó ẹrù rẹ̀ kúrò ni Russia lẹ̀yìn ti Belgium ṣíná fún wọn
Orilẹ-ede Belgium ti pegede fun ipele ''quarter finals'' ninu idije ife ẹyẹ agbaye ni orilẹede Russia.
Belgium fiya jẹ ikọ Japan pẹlu ami ayo mẹta si meji ninu ifẹsẹwọnsẹ wọn to waye lọjọ Aje.
Belgium yoo koju ikọ Brazil bayi ni ipele to kan.