Capoeira: ijó àwọn jagunjagun tó ń di ààyò àwọn ọ̀dọ́ lórílẹ̀èdè Brazil
Capoeira: ijó àwọn jagunjagun tó ń di ààyò àwọn ọ̀dọ́ lórílẹ̀èdè Brazil
Capoeira jẹ ijo kan to jẹ ilu mọọka lorilẹede Brazil. Adapọ ere idaraya ija jija ati ijo ni.
O jẹ ọkan lara awọn ohun amuyangan ti orilẹede naa n fi han awujọ agbaye ni.
Amọṣa itan fi idi rẹ mulẹ pe lati orilẹede Angola ni ijo naa ti ṣẹ wa ati wi pe awọn jagunjagun lo n lo o nigba iwaṣẹ gẹgẹbi ara ọna ati jafafa ati lati daraya.
- Àkọsílẹ̀ òfin mẹ́wàá tó pẹ́ jùlọ lórílẹ̀ ayé bọ́ sórí igbá fún títà
- Ọ̀rọ̀ ìṣẹ́ kò ká àwọn ọ̀dọ́ Nàìjíríà lára, orí ayélujára ni wọ́n ń fojojúmọ́ ń jóko sí - Pásítọ̀ Tobi Adegboyega Spac Nation
- Peller, gbajúmọ̀ Tiktok ṣàlàyé àṣírí àjọṣepọ̀ 'ọ̀rọ̀ ìfẹ́' tó wà láàrín òun àti Jarvis
- 'Mo kẹ́kọ̀ọ́ jáde ní fásitì, àmọ́ aṣọ ìtìjú mi ti fàya bí mo ṣe n fi súùtù kiri mọ́ín-mọ́ín'
Itan tilẹ tun tẹsiwaju lati sọ pe awọn ẹru ti wọn ko lati ilẹ Afrika ni wọn ko o wọ orilẹede Brasil lasiko ti owo ẹru ṣi gbilẹ lagbaye.
Nibayii, ijo yii ti n pada si orirun rẹ lorilẹede Angola. Nibayii awọn ọdọ orilẹede naa ti n rọ witiwiti lọ kọ ijo yii.






