Arsenal yóò kojú PSG, Liverpool àti Real Madrid yóò máa wàákò nínú ìdíje Champions League

Oríṣun àwòrán, EPA
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2
Ẹgbẹ agbabọọlu Real Madrid ti ife ẹyẹ UEFA Champions League wa lọwọ rẹ yoo maa waako pẹlu Liverpool ni isọri akọkọ idije naa ti saa bọọlu tuntun yii to ṣẹṣẹ bẹrẹ.
Ni irọlẹ Ọjọbọ ni ajọ UEFA kede awọn isọri tawọn ẹgbẹ agbabọọlu yoo wa fun saa bọọlu tuntun yii.
Lọtẹ yii, ẹgbẹ agbabọọlu mẹrindinlogoji ni yoo kopa ninu idije Champions League dipo ikọ agbabọọlu mejilelọgbọn to maa kopa ninu idije ọhun tẹlẹ.
Awọn ẹgbẹ agbabọọlu mii ti Liverpool yoo koju ni Dortmund, AC Milan, Atalanta, Salzburg, Lille, Stuttgart, ati Brest.
Wọnyii ni oriṣiiriṣii isọri awọn ẹgbẹ agbabọọlu alatako ti Arsenal, Liverpool, Man City ati Aston Villa yoo koju ni isọri akọkọ idije Champions League ti saa tuntun yii.
Arsenal
- PSG (h)
- Inter Milan (a)
- Shakhtar Donetsk (h)
- Atalanta (a)
- Dinamo Zagreb (h)
- Sporting CP (a)
- Monaco (h)
- Gerona (a)
Man City
- Bayern Munich (h)
- Borussia Dortmund (a)
- Atalanta (h)
- Benfica (a)
- Young Boys (h)
- Red Star Belgrade (a)
- Brest (h)
- Monaco (a)
Liverpool
- Real Madrid (H)
- Leipzig (A)
- Leverkusen (H)
- AC Milan (A)
- Lille (H)
- PSV Eindhoven (A)
- Bologna (H)
- Girona (A)
Aston Villa
- Bayern Munich (H)
- Leipzig (A)
- Juventus (H)
- Club Bruges (A)
- Celtic (H)
- Young Boys (A)
- Bologna (H)
- Monaco (A)











