Èyí làwọn àwòrán tó jojúńgbèsè láti ibi ayẹyẹ ìfinijoyè Olubadan tuntun ní ìlú Ibadan

Aworan eto ifinijoye Olubadan tuntun.

Aworan lati gbagede Mapo niluu Ibadan, nibi ti ayẹyẹ ifinijoye ati gbigbe ọpa aṣẹ fun Olubadan ikẹtalelogoji yoo ti waye.

Bakan naa lawọn aworan kan tun wa lati Agboolé Afọbajẹ Lábọ́sìndé, Ojaaba, Ibadan nibi ti iwure yoo ti waye fun Ọba Owolabi Ọlakulẹhin ki o to gba ọpa aṣẹ rẹ.

Eto ti n to, awọn alejo ni ọlọkan ojọkan ti n de si ibi eto naa. A n reti Gomina ipinlẹ Ọyọ, Onimọẹrọ Ṣeyi Makinde ati Olubadan tuntun, Ọba Owolabi Ọlakulẹhin, Ige Olakulẹhin 1, ki eto naa to bẹrẹ ni pẹrẹu.

Aworan eto ifinijoye Olubadan tuntun.
Aworan eto ifinijoye Olubadan tuntun.
Aworan eto ifinijoye Olubadan tuntun.
Aworan eto ifinijoye Olubadan tuntun.
Aworan eto ifinijoye Olubadan tuntun.
Aworan eto ifinijoye Olubadan tuntun.
Aworan eto ifinijoye Olubadan tuntun.
Aworan eto ifinijoye Olubadan tuntun.
Aworan eto ifinijoye Olubadan tuntun.
Aworan eto ifinijoye Olubadan tuntun.
Aworan eto ifinijoye Olubadan tuntun.
Aworan eto ifinijoye Olubadan tuntun.
Aworan eto ifinijoye Olubadan tuntun.
Aworan eto ifinijoye Olubadan tuntun.
Aworan eto ifinijoye Olubadan tuntun.
Aworan eto ifinijoye Olubadan tuntun.
Aworan eto ifinijoye Olubadan tuntun.