Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Njẹ o ranti fidio kan lori ayelujara to n ṣafihan bawọn ọlọpaa MOPOL ti n gbowo lọwọ ọmọ ilẹ China kan
Bẹẹ ni mo ranti, ki ni tuntun nipa fidio ọhun
Ileeṣẹ ọlọpaa ni ihuwasi awọn MOPOL naa tabuku iṣẹ ọlọpaa, atipe ijiya to tọ n duro de wọn
Kan soju opo BBC Yoruba fun ẹkunrẹrẹ
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Idajọ mii ree! Àwọn obìnrin tí wọn bí lóbìnrin nìkan ni òfin rí gẹ́gẹ́ bíi obìnrin
Ẹnh ẹnh, nigba wo lo d'adajọ?
Emi ma kọ ọ, ile ẹjọ to ga julọ lo dajọ pe awọn kosakọ-kasabo ko lẹtọọ sawọn anfaani to wa fawọn obinrin
ṣe ile ẹjọ to ga julọ ti Naijiria naa abi t'orilẹede mii?
Alaye wa lori ikanni BBC Yoruba
,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,
Njẹ o ti gbọ?
Pe kinni?
Wi pe WhatsApp kò ní bawọn foonu kan ṣiṣẹ́ mọ́ láti oṣù tó ń bọ̀
Ki lo ṣẹlẹ, ṣe iru foonu ti mo n lo ko ṣa si nbẹ?
Ti o ba fẹ mọ…kan soju opo BBC Yoruba
















