Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Ọjọ gbogbo ni tole,
Bẹẹ ni, ọjọ ni to l'ohun, ta lo jale ta ni wọn mu?
Ileeṣẹ ologun Naijiria lo ti mawọn soja mejidinlogun ati ọlọpa kogberegbe mẹẹdogun
Lori ẹsun pe wọn ko ibọn fawọn ẹgbẹ alakakiti ẹsin
ọba ilu kan ati araalu mẹjọ lo wa lara awọn afurasi ọhun
Kan soju opo BBC Yoruba fun ẹkunrẹrẹ
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Ẹ forinjin wa!
Ta lo ṣẹ to n tọrọ aforojin?
Ajọ WAEC lo tọrọ aforijin lọwọ awọn obi ati akẹkọọ lori bi wọn ṣe kuna lati tete bẹrẹ idanwo asejade l'Ọjọru ọsẹ yii
Agbẹnusọ ajọ naa sọ pe ọwọ WAEC lasise ti wa
Ki ni WAEC wa sọ pe o ṣokunfa aitete bẹrẹ idanwo ọhun?
Idahun wa loju opo BBC Yoruba
'''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Bí Tinubu kò bá wá nǹkan ṣe sọrọ ètò ààbo mẹ́hẹ ati ọro aje, kò sí àṣeyọ̀rí kankan tó ṣe
Olukọ agba ni fasiti, Ọjọgbọn Gbade Ojo, lo sọ bẹẹ lasiko to n ṣe agbeyẹwọ ijọba Tinubu lẹyin to pe ọdun meji nijọba
O ni Ọpọ awọn agbẹ lo ti fi oko wọn silẹ tori eto aabo to mẹhẹ
















