Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

N jẹ o ti gbọ?

Pe kinni?

Wi pe gbogbo olokowo to ko ba tii forukọ owo wọn silẹ pẹlu ijọba gbọdo ṣe bẹẹ laarin ọsẹ mẹfa, bi bẹẹ kọọ

Hmm kini yoo ṣẹlẹ?

Irufẹ olokowo bẹẹ le dero ẹwọn!

Ẹwọn bawo? Ṣawọn eeyan to n ta worobo naa yoo forukọ silẹ bayii?

Lọ sori ikanni BBC Yoruba, ti o ba fẹ mọ

'''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''

Ofin to mu Eleegun lo mu ẹlẹha o

Tawọn aṣofin ba le fẹgbẹ oṣelu wọn silẹ darapọ mẹgbẹ mii

Awọn gomina naa le ṣe bẹ

Agbẹjọro agba Yomi Aliu lo fidi ọro yii mulẹ

Lẹyin ti igbimọ alaṣẹ PDP sọ pe awọn yoo gbe Gomina ipinlẹ Delta

To fẹgbẹ naa silẹ darapọ mọ APC lọ ile ẹjọ.

''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''

Iroyin to n tẹ wa lọwọ lo sẹ pe Ajọ EFCC ti fi gbajumọ ọdọmọde olowo, Emeka Okonkwo Daniel ti ọpọ eeyan mọ si E-Money silẹ

Lẹyin ti wọn ṣe ifọrọwanlẹnuwo pẹlu rẹ tan

Lori ẹsun nina owo dọla loju agbo ode ijo kan laipẹ yii.

Fun ẹkunrẹrẹ…