Ọmọọbabìnrin Adesile tó ń fi ẹṣin dábírà l'Ojude Oba

Àkọlé fídíò, Ọmọọbabìnrin Adesile tó ń fi ẹṣin dábírà l'Ojude Oba
Ọmọọbabìnrin Adesile tó ń fi ẹṣin dábírà l'Ojude Oba

Ọmọbabinrin Adesile ṣalaye pe adura ni wọn fi n tẹlẹ ẹṣin gigun lọ sojude ọba ki wọn to bọ sode.

O ni oludaleeṣẹ silẹ to ni ọpọ ileeṣẹ ni oun amọṣa lati kekere ni o ti n wu oun lati gun ẹsin ṣugbọn gẹgẹbi ọmọọba, awọn obi oun ko gba oun laye nitori pe wọn ni wọn maa wa n ki ọba ati idile rẹ lojude ọba ni ko yẹ ki ọmọọba tun maa gun ẹsin nibẹ.