Ìgbà mẹ́rin ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni ìyá mi ti bí ọkùnrin àbíkú kí wọ́n tó bí mi - Ọ̀jọ̀gbọ́n Wande Abimbola tó dífá Aláàfin Oyo
Ìgbà mẹ́rin ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni ìyá mi ti bí ọkùnrin àbíkú kí wọ́n tó bí mi - Ọ̀jọ̀gbọ́n Wande Abimbola tó dífá Aláàfin Oyo
Agba awo Ogunwande Ifagbemi Sangodahunsi, lo jẹ Awisẹ Agbaye fun gbogbo Babalawo ati ọkan ninu awọn Awo fun Ọọni tilu Ile Ife.
O ṣalaye pe igba mẹrin ọtọọtọ ni iya oun ti bi abiku lọkunrin to si jẹ pe baba oun ko fẹ ki oun kawe tabi lọ si ile ẹkọ.