Ohun tó yẹ kí o ṣe bí nǹkan bá sá pá ọmọ rẹ lórí?
Ohun tó yẹ kí o ṣe bí nǹkan bá sá pá ọmọ rẹ lórí?
Njẹ o mọ ohun ti o yẹ ni ṣiṣẹ nigba ti ounjẹ ba sa pa ọmọ rẹ lori?
Mimojuto awn ọmọde ti nnkan bi ounjẹ tabi omi tabi nnkan miran ba sa pa lori tabi ko si lọfun jẹ ara ipenija ti ọpọ awọn obi maa n ni.
Nitoripe iṣẹlẹ pajawiri ni iṣẹlẹ yii maa n jẹ, o nilo ki awọn obi tabi agbalagba ti ọmọ ba wa lọwọ rẹ tabi to ba wa niayika ti nnkan yii ba ti ṣẹlẹ o mọ ohun to tọ ni ṣiṣe.
Alaye awọn ohun to yẹ ki o ṣe ni igbesẹ de igbesẹ wa ninu fidio yii.






