Sheikh Muyideen Ajani Bello ṣe àdúrà ọdún fún wa ní ìlànà ẹ̀sìn Islam
Sheikh Muyideen Ajani Bello ṣe àdúrà ọdún fún wa ní ìlànà ẹ̀sìn Islam

Eekan lara awọn aṣiwaju ẹsin Islam lorilẹede Naijiria ati Lagbaye ni Alhaji Sheihk Muyideen Ajani Bello.
Koko Adura wọn naa ni ki Ọlọrun o tẹ gbogbo ọmọ Naijiria ati gbogbo eeyan lagbaye lọrun.
Bakan naa lo tun gbadura fun idẹra fun gbogbo eniyan ninu ọdun tuntun.