Àwọn awakọ̀ ti bẹ̀rẹ̀ sí ní tò ra epo pẹ̀lú bí owó epo ṣe ń lọ sókè
Àwọn awakọ̀ ti bẹ̀rẹ̀ sí ní tò ra epo pẹ̀lú bí owó epo ṣe ń lọ sókè
Awọn awakọ kaakiri agbaye ti sọrọ lori bi owo ori epo ṣe n gbẹnu soke koda to ti ju ọgọrun dọla.
Ohun ti ọpọ wọn n ṣe bayii ni lati maa ra epo ko pamọ. Ogun to n ṣẹlẹ pẹlu ikọlu Amẹrika ati Israel si Iran ti mu ki owo epo ru gọgọ sii pẹlu bi awọn kan ṣe n woye pe o ṣeeṣe ki i adinku ba iye jala epo to ba n yọ.
Awọn alaṣẹ lorilẹede South Korea ati Thailand ti sọ pe awọn yoo fi gbedeke si iye ti owo ori epo le jẹ.





