Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Ẹ ṣe Kabiyesii ooooooo
Kabiyesii oo
Ọmọọba Abimbọla Akeem Owoade lọmọ oye ti wọn yan lati joko sori itẹ Alaafin Oyo
Ijọba ipinlẹ Ọyọ lo kede eyi lọjọ Ẹti
Wọnni orukọ rẹ lo yọ lẹyin ti wọn gbe ifa janlẹ ti wọn si ṣe ayẹwo gbogbo lọna iṣẹṣe
Ọdun mẹta din diẹ ree ti Alaafin ana, Ọba Ọlayiwọla Adeyẹmi kẹta waja
xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx
Awọn agbesunmọmi kọlu ibudo agbara ikọ ọmọ ogun Benin, wọn pa ọmọ-ọgun mejidinlọgbọn danu
Ilẹ Niger ati Burkinafaso to jẹ alamuleti wọn ni wọn sọ pe ikọlu ọhun ti rugbo wa
Ọgagun Faizou Gomina, olori ọmọ ogun Benin ṣalaye pe alẹ Ọjọru to kọja ni ikọlu ọhun waye
Sare lọ soju opo BBC.COM/Yoruba fun ẹkunrẹrẹ
XXXXXXXXXXXXXXXXXXXXXXXX
Njẹ o mọ pe aala wa laarin biba ọmọ wi ati ifiyajẹ ọmọde?
Awọn onimọ ba BBC sọrọ lori ariwo to sọ lori olukọ kan to lu ọmọ nilukulu laipẹ yii l'Eko
Wọn ni lilo ẹgba, bẹliiti ati awọn nnkan miran ko si ninu ilana biba ọmọ wi mọ lagbaye
lati gbọ ẹkunrẹrẹ ohun ti wọn sọ
Ẹ kan soju opo bbc.com/yoruba

