Àwọn olùgbé ìlú kékeré yìí ní England ń wá àwọn Dókítà tó leè ṣiṣẹ́, wo orin aládùn tí wọ́n máa ń kọ nígboro fún ìkéde
Àwọn olùgbé ìlú kékeré yìí ní England ń wá àwọn Dókítà tó leè ṣiṣẹ́, wo orin aládùn tí wọ́n máa ń kọ nígboro fún ìkéde
Dokita mẹsan lo ti fi ifẹ han bayii lati wa ṣiṣẹ ni ilu naa laarin ọsẹ kan ti wọn ti bẹrẹ orin kikọ yii nita gbangba.
"A ni iṣẹ abẹ to n duro de ọ,
Bẹẹ la si ni owo too ba fẹ...
Ibi to dara yatọ gan lati gbe ni..."
Ilu Lostwithiel ni awọn ara agbegbe to ni oniruuru ẹbun to dara ti Ọlọrun da mọ wọn, gẹgẹ bi Michelle Ninehan ṣe sọ fun BBc ninu ifọrọwanilẹnuwo.

Iwadii fihan pe Dokita bii ẹgbẹrun mọkandinlogun lo n fi iṣẹ silẹ laarin ọsẹ marun nilẹ Gẹẹsi, iru awọn kekere
Wọn ni awọn n wa Dokita to dara, awọn si ni awọn ohun meremere to lee wu ni ni
Gbogbo awọn ara adugbo naa wa parapọ ni ọna tuntun lati fi kede pe awọn nilo Dokita to dara ti yoo maa tọju awọn.






