Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
O ti deewọ!
Ki lo deewọ?
Ẹnikẹni tabi ajọ yoowu to ba fẹ pin ounjẹ ọfẹ fun igba ati aadọta eeyan nipinlẹ Eko
Ko gbọdọ ma forukọ silẹ pẹlu ijọba atawọn ẹṣọ eleto abo
Igbesẹ yii ko ṣeyin ati dena irufẹ iṣẹlẹ itẹra-ẹni-pa to waye n'Ibadan, Abuja ati Anambra
Ki lawọn ipinlẹ yoku sọ lori ọrọ naa?
Kan soju opo BBC.Com/Yoruba fun ẹkunrẹrẹ
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Ẹ lọ fọkan balẹ
Igbakeji aarẹ Kashim Shettima ti fọkan awọn araalu balẹ wi pe
gbogbo awọn to padanu ẹmi wọn nibi iṣẹlẹ itẹra-ẹni-pa to waye lọsẹ to kọja
n'ijọba yoo ṣe'ranwọ fun ẹbi wọn
Shettima ni adanu nla ni iṣẹlẹ naa jẹ fun gbogbo Naijiria
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
A o ni figba kan bọkan ninu lori wadii ohun to ṣokunfa iku Jimoh Olatunji lahamọ ọlọpaa n'Ilorin
Ọgba agba ileeṣẹ ọlọpaa Naijiria, Kayode Egbetokun, lo ṣeleri bẹẹ nigba to ṣabẹwo ibanikẹdun si ẹbi oloogbe naa
ṣaaju ni ẹgbọn oloogbe sọ fun BBC Yoruba pe awọn ọlọpaa ni Olatunji pokunso ni lahamọ nigba tẹbi rẹ beere ohun to ṣokunfa iku rẹ
Fun ẹkunrẹrẹ iroyin naa....
















