Iriri agba: Ojogbon Ayodele Desalu : Nǹkan tójú àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Nàìjíríà ń rí lókè òkun kọjá àfẹnusọ
Yorùbá bọ̀ wọ́n ní ohun tí ojú àgbà rí tí ojú àgbà fi jìn, bí ọmọdé bá rí i ó ṣeéṣe kí ojú náà fọ́ pátápátá.
Ọ̀jọ̀gbọ́n Ayodele Desalu tí ilé ẹ̀kọ́ gíga fásitì ìlú Ibadan nígbà tó ń BBC Yorùbá sọ̀rọ̀ nípa ìrírí wọn lẹ́nu ẹ̀kọ́ kó tí wọ́n sì rò lórí àwọn nǹkan tí ojú wọ́n rí kí wan tó dé ipò tí wọ́n wà lónìí.
Ọ̀jọ̀gbọ́n Desalu ṣàlàyé pé bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹlẹ́kọ̀ọ́ ni àwọn òbí òun síbẹ̀ ọ̀pọ̀ ìgbà ni òun tún kíláàsì kan ní ẹ̀ẹ̀mejì ó kéré tán nígbà tí òun fi wà lẹ́nu ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àmọ́ àìkó àárẹ̀ ọkàn ní òun fi di Ọ̀jọ̀gbọ́n lóde òní.
Ó ní pé ọ̀pọ̀ àwọn ọmọ Nàìjíríà tí wọ́n bá dé òkè òkun ni wọ́n máa ń ṣe dáadáa àti pé ọ̀pọ̀ nǹkan tí ojú akẹ́kọ̀ọ́ Nàìjíríà máa ń rí nílẹ̀ òkèrè kò kéré rárá.
- 'Mi ò lọ sí ilé ẹ̀kọ́ kankan ẹ̀bùn tí Ọlọ́run fún mi ni mo fi ń ṣe ọkọ̀ òfurufú'
- Owó oṣù 'Professor' ju ti 'Perm Sec' lọ nígbà tí mo bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní 1963- Emeritus Ayo Bamgbose
- Níbo lẹ ti gbọ́ pé mo kọ ọkọ mi sílẹ̀ ló fẹ́ Pasuma?, Bí ọ̀rọ̀ ìfẹ́ èmi àti Paso ṣe bẹ̀rẹ̀ rèé- Jaye Kuti
- Àsìkò wo ló yẹ kí obìnrin bẹ̀rẹ̀ ìbálòpọ̀ padà lẹ́yìn ìbìmọ láìséwu?
- 'Tí wọ́n bá bá ẹ sùn tí wọn ò "release" wọ́n á gba owó wọn, àwa la ń ra Kọ́ńdọ́ọ̀mù tí wọ́n fi ń bá wa sùn ní Mali'
- Hijab kò dí mi lọ́wọ́ láti di obìnrin agbábọ́ọ́lù láì náání yẹ̀yẹ́ - Zulfah Abdulazzez
- Ṣé lọ́ọ̀tọ̀ ní àkúdááyà wà? ẹ̀ wo ìrírí àwọn tó rí ènìyàn wọn tó kú láàyè
- 'Ọ̀pọ̀ ọ̀dọ́ tó lágbára jù wọ́n lọ lò ṣì ń wá iṣẹ́ nítorí náà kò dára tó'
- Wọ́n lẹ̀ mí lókò, wọ́n lé mi kúrò lẹ́nu iṣẹ́ oùnjẹ ti mò ń tà lẹ́yìn ti mo ṣeré ìkà lọmọ ejò- Iya 2D
- Ilé ẹjọ́ fi méjì nínú àwọn tó lu Temitope Olorunfemi pa lórí ẹ̀sùn Yahoo pamọ́ sọ́gbà ẹ̀wọ̀n, gba béèlì mẹ́ta