Bamise BRT bus Court case: Ohun tó ń ṣẹlẹ̀ nílé ẹjọ́ tí dẹ́rẹ́bà ọkọ̀ BRT tí Bamise wọ ti jẹ́jọ́ rèé

Dẹ́rẹba BRT

Iroyin to n tẹ wa lọwọ ni yajoyajo sọ pe àwọn ti ọ̀rọ̀ kàn ti péjú sí ilé ẹjọ́ Majisireeti Yaba fun igbẹjọ iku Bamise Ayanwole.

Akroyin BBC Yoruba to wa nibẹ fi awọn aworan ranṣẹ to n ṣafihan bi wọn ṣe ko ṣẹkẹṣẹkẹ si dẹrẹ́ba naa lọwọ ti wọn n gbe e lọ si ile ẹjọ̀.

Dẹrẹba ọkọ BRT

Ni ile ẹjọ Majisireeti to wa ni agbegbe Yaba ni ipinlẹ Eko ni igbẹjọ naa ti waye.

Bi awọn oniroyin to wa nib ṣe woye, o jọ pe ni kete ti dẹrẹba naa de ile ẹjọ ni wọn ti dari rẹ lọ si ibi ti awọn eeyan to mọ pe wọn ti baba lọ si inu ile jọ ni.

Àkọlé fídíò, Mo bá Obasanjo ṣiṣẹ́pọ̀ gẹ́gẹ́ bí ológun àti nínú oko, ìdí tí ẹ̀mí rẹ̀ fi gùn rèé - Olórin Amona tete bo

Akroyin BBC Yoruba to wa nibẹ fi to wa leti pe adajọ ti dajọ pe ki wọn gbe dẹrẹba naa lọ ẹwọn Kirikiri pe ibẹ ni yoo wa titi gbogbo asiko ti wọn yoo maa da ẹjọ rẹ.

Ile ẹjọ Majisireeti
D
Àkọlé fídíò, 'Hááà! Bamise mà jìyà o, ó l'óun á mu mi kúrò nílé àyágbé àmọ́ ó wá di ẹni tí wọ́n yọ pátá lára rẹ̀'
Àkọlé fídíò, Ṣé ó lòdì sí òfin Ọlọ́run kí Krìstẹ́ni jẹ Ọba ilẹ̀ Yorùba? Pásítọ̀ ìjọ Deeper Life sọ ìran tó rí tó fi gbà láti jẹ Ọba