WhatsApp new update: Tóò bá ń dédé sọ fótò tàbí fídíò nù lórí fóònù, Watssap ló gbé ètò tuntun jáde ó!

WhatsApp

Oríṣun àwòrán, WhatsApp

Aapu Watssap ṣẹ̀ṣẹ̀ ja àwọn aato tuntun kan tí yóò gbà àwọn tó ń loo láàyè láti rí fọto wọn tàbí fídíò tó máa sábà pòórá lẹ́yìn tí wọn ba ti rii.

Ṣe ẹ ṣàkíyèsí pé tẹẹ bá ti sì fọto náà fún ìgbà àkọ́kọ́, tí ẹ wo ó leekan tó sì parẹ lai fi pamọ sórí fóònù.

Watssap tí ni anfani ààtò tuntun tí àwọn gbé jáde yìí ni lati fún àwọn tó ń loo ni anfani àti leè ni aaye ikọkọ ara wọn lórí fóònù.

Ẹwẹ, àwọn ajafẹtọ ọmọdé àti ohun tó yẹ kí wọn máa wò ní aapu tó ń pá fọto àti fídíò rẹ náà dára pupọ torí yóò lè seranwo láti fi aridaju ifipa bá ọmọdé lọ pọ pamọ.

Nítorí èyí, ẹgbẹ́ àwọn tó ń dá abo bo ẹtọ àwọn ọmọdé tí kò sì ọ̀rọ̀ pẹ̀lú ileese to jẹ ìyá Whatssap, ìyẹn Facebook lórí ọrọ yìí.

Àwọn ọ̀rọ̀ ikọkọ náà túmọ̀ sí wí pé Ọlọpaa kò ní leè rí atejise náà, ẹni tó kọ ọ àti ẹni tó gbà á ní esi nìkan ni yóò rii sugbọn aapu èyí tó ń pá ọrọ rẹ kíákíá leè túmọ̀ sí pé àwọn fóònù tí Ọlọpaa bá gba lọwọ ẹni tí wọn ba mú kó ni ni aridaju ẹri ti wọn n wa.

Èyí sì tún wá leè fi àwọn ọmọdé sì ewu tó pọ̀ nípa fífún àwọn tó bá ṣe wọn níbi lanfani àti má leè fi òfin gba wọn mu tí wọn yóò sì pá ẹri rẹ.

"Nigbati akitiyan láti fòpin sí ifipa bá ọmọdé lọ pọ bá tún wà forí san pọn torí èyí", Allison fi ọ̀rọ̀ lọ ọga eka ààbò ileese naa.

Aworan idanimo WhatsApp

Oríṣun àwòrán, Reuters

Watssap ni tiwọn ń sọ pé afiwe ohun tí àwọn ṣe kan je ohun too lè lọ fúnra rẹ ni - bíi too bá ń rà aṣọ too ni kí èèyàn kan yẹ ọ wò boo ṣe rí, tàbí kọọ fi nomba password rẹ ranse sì èèyàn kan.

Kii ṣe gbogbo nkan ti a ba pín lọ pọn dandan kí gbogbo èèyàn gbà, ileese Watssap lọ sọ bẹẹ.

"Lórí ọpọlọpọ fóònù, yíya fọto lasan túmọ̀ sí pé yóò gbà ààyè lórí Kamẹra fóònù rẹ títí láé".

Ní wón be gbé ààtò tuntun yẹn jáde fún gbogbo ènìyàn tí yóò sì bẹ̀rẹ̀ lọṣe yìí.

Kí ni ìwúlò rẹ?

Ẹni tó ń lọ fóònù yóò lè mọ pe ọ̀rọ̀ atejise, wiwo ó leekan ni báyìí toripe atunwo rẹ yóò fara pamọ tí "icon" ńlá kan tí yóò kó "1" soju ni yóò sì jáde dípò rẹ koo lè mọ.

Yóò kan dabii pé ọ̀rọ̀ atejise rẹ dédé pòórá bo se maa n rí lórí Snapchat, sugbọn ó sì ṣeéṣe kí òní nkan yà fọto "screenshot" rẹ tàbí gba fídíò ọ̀rọ̀ naa silẹ nígbà tó bá sí í fún ìgbà àkọ́kọ́ tàbí kó Kamera ojú èwe kan pẹ̀lú Kamera mìíràn.

Àkọlé fídíò, Esabod, Sunday Igboho: Kò burú bí Igboho ṣe wà lẹ́wọ̀n báyìí,ọ̀rọ̀ rẹ̀ dàbí i ti aláboyún

Àbùdá ààtò tuntun yìí lórí fóònù rẹ

Fọto náà kò ní pamọ sì ibi ìpamọ́ phone gallery.

Óò ní lè fi fọto náà ranse, fi pamọ, pín in tàbí máa kí rẹ gẹgẹ bii ara ọ̀tọ̀.

Ọjọ́ yóò lọ lórí rẹ (expire) tí ó kó bá sii laarin ọ̀sẹ̀ méjì.

Ẹwẹ, ileese náà tí sọ pé àwọn ń ṣe eto lati rii pe awọn tó kàn ileese kò parẹ.