Iyalaje Oodua: Toyin Kolade ṣàlàyé ìdí tí Ooni Ogunwusi ṣe fi jẹ Ìyálájé Oodua fún gbogbo ilẹ̀ Yorùbá lágbáyé
Kaakiri agbaye ni ọrọ Aje ko ti jẹ eyi ti a n fi ọwọ yẹpẹrẹ mu.
Aje ogugunisọ, onisọ iboji.
- Wọ́n ti sìnkú Ọ̀gágun àgbà Huseini Ahmed tí agbébọn pa, bó ṣe lọ rèé
- Cubana Chief Priest ra màálù 46 fún ìsìnkú ìyá ọ̀gá rẹ̀, àwọn ọmọ Naijiria ń fi èrò wọn hàn
- Ẹ̀yin oníròyìn ẹ rọra máa pariwo ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ nípa àwọn adigunjalè, ẹ ń kóbá iṣẹ́ agbófinró - Àjọ NBC
- A ò jà lórí ẹni tí yóò rọ́pò TB Joshua, ìyàwó rẹ Evelyn ló ń darí ètò báyìí- Ìjọ́ Synagogue
- Mọ̀ si nípa agbẹjọ́rò Yoruba Nation tó gbé Buhari lọ sílé ẹjọ́ àgbáyé ICC
Gẹgẹ bi itan iṣẹdale, aje lo wa ni idi ki ọmọ ẹda ri na ko ri lo, aje ọhun gan ni alakoso gbogbo karakata lagbaye.
Iyalaje oodua fun gbogbo ọmọ Yoruba kariaye, loye Toyin Kọlade ba BBC News Yoruba sọrọ lori pataki aje, iyatọ rẹ si iyalọja ati bi o ṣe ṣe pataki fun obinrin to ba fẹ ri ti aje ṣe lati maa tẹriba fun ọkọ wọn.