Tolulope Adeleke Aire: Mo wòye pé àwọn ọkùnrin Nàìjíríà kò fi bẹ́ẹ̀ mọ̀ nípa ìtọ́jú ọmọ tuntun
Tolulopa Adeleke Aire ṣalaye idi to fi gbe eto itọju ikoko kalẹ fun awọn baba ọmọ tuntun.
Eyin alaboyun, kii ṣe ẹyin nikan ni ẹ le da ọmọ yin tọ o.
Tọkọtaya ti wọn jọ fun ara wọn loyun naa ni ki wọn jọ tọju ikoko naa.
- 5:30 p.m ni ojú mi déédé fọ́ níbi tí mo ti ń darí ọkọ̀ ni Ọrẹgun Ikẹja -LASTMA Yesufa
- Ẹ̀kún l'oúnjẹ́ mi ní ọ̀pọ̀ ìgbà lẹ́yìn tí ojú mi fọ́ ní JSS 3- Lawal Ayankemi
- Wo àwọn sinimá mẹ́wàá tó gbé sinimá Yorùbá sáyé
- Ẹ wo ẹranko (Akíka) tó ṣeéṣe kó ní ǹkan ṣe pẹ̀lú àrùn Coronavirus!
- Wo ǹkan mẹ́fà tó yẹ kí o mọ̀ nípa Sunday Igboho tí orúkọ rẹ̀ gbẹnu aráyé kán
Ona abayọ si iṣoro aini oluranlọwọ ni Noọsi Tolulọpẹ Adeleke Aire n kọ awọn ọkunrin.

Akọṣẹmọṣẹ nọọsi ni Naijiria ati ni Ilẹ United Kingdom ni Tolulope Adeleke Aire to n kọ awọn ọkunrin ni Naijiria lati tun ero wọn pa nipa riran iyawo wọn lọwọ lati tọju ikoko.
O n kọ wọn nipa igbẹbi, itọju alaboyun ati ẹni to ṣẹṣẹ bimọ tuntun sọwọ.
- Ṣé lọ́ọ̀tọ̀ ní àkúdááyà wà? ẹ̀ wo ìrírí àwọn tó rí ènìyàn wọn tó kú láàyè
- Ẹ yé ṣí ìhòhò ara yín síta lórí ayélujára torí ‘Silhouette Challenge’ - Adeboye
- Òfin kónílé-ó-gbélé gbòde nílùú Igangan lórí ẹ̀rù pé Fulani le k'ógun wá lẹ́yìn àbẹ̀wò Igboho
- Èèyàn mẹ́tàdínlógún(17) jọ́ná ráúráú nínú ìjàmbá ọkọ̀ bọ́ọ̀sì lópòpóónà Bode-Saadu sí Jebba
- Wo bí o ṣe lè di ọmọ onílùú ní Dubai pẹ̀lú òfin tuntun orílẹ́èdè U.A.E.



