Jude Chukwuka: Wò ó bí òwé Yorùbá ṣe yọ̀ lẹ́nu ọmọ Igbo
Jude Chukwuka, tii se ọmọ Igbo, amọ to gbọ ede Yoruba tun ti gbe tuntun de.
Lọtẹ yii, owe ati awọn asayan ọrọ ni gbajumọ elere tiata naa tun gbe de.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
Chukwuka ninu fidio yii salaye awọn owe gbankọ meji ni ede Yoruba, itumọ wọn ati awọn iwulo wọn pẹlu.
Iyalẹnu si ni yoo jẹ fun ojulowo ọmọ Yoruba ti ko le da owe kankan pa, pe ọmọ ẹya Igbo tun gbọ owe Yoruba ju lọ.
- Ṣẹ gbọ́ nípa Alájọ Ṣómólú, tó ta mọ́tò ra kẹ̀kẹ́?
- Ẹfunroye Tinubu - Ògbóǹtagí oníṣòwò, olówò ẹrú àti afọbajẹ
- Samuel Ajayi Crowther, òjíṣẹ́ Ọlọ́run tó gbé èdè Yoruba lárugẹ
- Mọrèmi Àjàṣorò, akọni obìnrin tó gba Ilé Ifẹ̀ sílẹ̀ lóko ẹrú
- Ọ̀rọ̀ǹpọ̀tọ̀niyùn, Aláàfin obìnrin àkọ́kọ́ rèé, tó ní nǹkan ọkùnrin
- Baṣọ̀run Gáà, tó yan ọba mẹ́rin, pa ọba mẹ́rin àmọ́ ọba karùn-ún ló pa á



