Oba Adeyeye Ogunwusi: Ojú mi ti rí lọ́pọ̀ lọpọ̀, ọ̀pọ̀ èèyàn ni kò tilẹ̀ gbàgbọ́ pé mo lè jọba- Ooni
Irin ajo mi kun fun oriṣiiriṣii iṣẹlẹ nla ṣugbọn mo dupẹ lọwọ Ọlọrun O ka mi yẹ.
Ooni Ile Ife, Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi lo sọrọ yii nigba to n dupẹ lọwọ Eleduwa fun anfaani ti o ni lati pe ọdun marun un lori itẹ baba rẹ.
Ọba Ogunwunsi ni oju oun ti ri lọpọ lọpọ ninu irin ajo ki oun to jọba.
Ooni sọ pe irin ajo oun kun fun oriṣiiriṣii iṣẹlẹ nla, ati pe ọpọ ni ko gbagbọ pe oun le de ori ọtẹ gẹgẹ Ooni Ile Ife.
Oba Ogunwunsi ni oni ni a ri ko si ẹda to mọ ọla, o ni oun ko le dupẹ tan lọwọ ọlọrun.
- Ìdí rèé táwọn àkàndá ẹ̀dá fi dí iwájú iléeṣẹ́ ìjọba ìpínlẹ̀ Oyo pa l'Agodi n'Ibadan
- Kò sí ẹnikẹ́ni tó kú níbi rògbòdìyàn tó wáyé lánàá - Deji ilu Akure
- Ọlọ́pàá, sójà yabo Lekki Toll Plaza láti dènà ìfẹ̀hónúhàn míràn
- Idi ti Odili fi gba ibi ìbálòpọ̀ lọ sí ọ̀run alákeji nílùú Port Harcourt
- Makinde, Dele Momodu ń ṣèdárò Àgbà Oyè Ilẹ̀ Ibadan, Harry Akande tó jáde láyé





