Mistura Oseni Akintunde: Ara múmú kìí ṣe oríṣun ìfipábánilòpọ̀, ìran àwòjù ló ń fà á
Kii saba wọpọ ki eeyan ri obinrin Musulumi nita lati maa sisẹ wolii, gẹgẹ bawọn obinrin ẹlẹsin Kristẹni ti n se.
Amọ ti Wolii obinrin Mistura Oseni Akintunde yatọ, ẹni to n sisẹ wolii nilana ẹsin Islam yatọ.
Nigba to n ba BBC Yoruba sọrọ lori iwa ifipabanilopọ, Wolii Akintunde ni kii se bi obinrin ba se mura lo n fa iwa ifipabanilopọ, gẹgẹ bi awọn eeyan kan se lero.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Wo iye àwọn tó ti gbẹ̀mí ara wọn ní Nàìjíríà láàrin ọdún mẹ́rin ìjọba Buhari
- Gbèsè Nàìjíríà ti lé ní 18 tírílíọ́ọ́nù lábẹ́ ìṣèjọba Ààrẹ Buhari- DMO
- Wo bí iṣẹ́ abẹ wákàtí mẹ́fà, tí wọ́n fi dóòlà ẹ̀mí ìjàpá tí ọkọ̀ tẹ̀, ṣe lọ
- Kò sóhun tó ń jẹ́ ‘Captivus’ nílẹ̀ Oodua, mágùn ni mágùn ńjẹ́ - Babaláwo
- Wo àwọn obìnrin abúlé kan tó dáwó ra ọkọ̀ láti máa gbé aláboyún lọ ilé ìwòsàn
- Ìtàn rèé nípa bí Ogbomoso ṣe pa ọba, yọ nǹkan ọkùnrin rẹ jó kiri ìlú
Amọ o salaye pe bi a ba se wo ara wa loju si, boya ọkunrin ni abi obinrin lo n fa iwa ifipabanilopọ.
Akintunde fikun pe, kii se awọn ọkunrin nikan lo n huwa ifipabanilopọ, gẹgẹ bi awujọ wa se lero, amọ awọn obinrin gan n fipa bani lopọ, ko si yẹ ka maa pariwo awọn ọkunrin nikan.
- Ìtàn ayé Henry Fajemirokun, olówó tó fi owó mọ Olúwa àti ènìyàn
- Ìtàn ayé Taiwo Oredein rèé, àgbà òṣèlú tó parí ayé rẹ̀ sọ́gbà ẹ̀wọ̀n
- Ìtàn ìgbé ayé Bode Thomas rèé, ó kọ́ wa láti máa kó ẹnu wa ní ìjánu
- Ṣo mọ̀ pé J.F Odunjo jẹ aṣòfin àti mínísítà nílẹ̀ yìí, yàtọ̀ sí pé ó jẹ́ òǹkọ̀wé?
- Ó pé ọdún mẹ́rìnlélàádọ̀ta tí Akintola kú, ìdí abájọ ìja rẹ̀ pẹ̀lú Awolowo rè é
O wa tako ẹwọn ọdun mejidinlogun ti wọn n fun awọn eeyan to n fipa bani lopọ, eyi to ni ko to fun ijiya ẹsẹ wọn .
Bakan naa lo rs awọn eeyan lati ye ko awọn ti wọn ba fi tipa ba lopọ laya jẹ lori ayelujara, amọ n se lo yẹ ki wọn sewuri fun wọn lati jade sita sọ tẹnu wọn.