Douye Diri: Ìgbìmọ̀ olùgbẹ́jọ́ ẹ̀hónú ìbò yẹ àga mọ́ Gómìnà Bayelsa nídìí

Gomina Douye Diri

Oríṣun àwòrán, Others

Ile ẹjọ to n gbọ ẹhonu ibo gomina nipinlẹ bayelsa ti wọgile ibo to gbe Gomina Douye Diri ati igbakeji rẹ, Lawrence Ewhrudjakpo wọle.

Ninu idajọ ti adajọ Yunusa Musa gbe kalẹ lori ẹhonu ibo gomina ti ẹgbẹ oselu ANDP gbe wa siwaju rẹ, igbimọ olugbẹjọ ẹhonu ibo naa ni ajọ eleto idibo lo yọ orukọ oludije ibo gomina fun ẹgbẹ oselu naa lọna aitọ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Igbimọ olugbẹjọ naa wa pasẹ fun ajọ Inec lati tun eto idibo gomina mii se nipinlẹ Bayelsa laarin aadọsan ọjọ pere.

Bakan naa lo tun fikun pe, ajọ eleto idibo gbọdọ fi olupẹjọ naa, eyiun ẹgbẹ oselu ANDP sinu eto idibo tuntun.

Àkọlé fídíò, Blind DJ: Etu Omotayo kò ríran àmọ́ ó le to irinṣẹ́ eléré pọ̀ láti kọrin láì sí ìrànwọ́

Ẹ jọwọ, ẹ tun oju opo iroyin yi yẹwo, ki ẹ lee ri ẹkunrẹrẹ iroyin ọtun laipẹ.