Rape: Oríṣí ìjìyà ní àwọn bíi Gómìnà El Rufai àti Fayemi ń bèèrè f'àwọn afipábánilòpọ̀

Àkọlé fídíò, Oríṣí ìjìyà ní àwọn bíi Gómìnà El Rufai àti Fayemi ń bèèrè f'àwọn afipábánilòpọ̀

Nibo ni ọrọ ile aye n lọ bayii lori ifipabanilopọ?

BBC Kayeefi oṣu kẹfa yii lọ si Ado Ekiti nibi ti ọmọbinrin kan ti wọn fipa ba lopọ loke ọja ti ṣe iranlọwọ fun awọn agbofinro ti ọwọ si tẹ awọn ọdọmọkunrin oniṣẹ ibi naa.

Kọmiṣọnna ọlọpaa ni ipinlẹ Ekiti, Amba Asuquo kilọ fun awọn obi lati mojuto awọn ọmọ wọn obinrin to n kiri ọja.

Bakan naa ni awọn eeyan ati ajafẹtọ ọmọniyan sọ iriri wọn lori ifipabanilopọ ni eyi ti o yẹ ki gbogbo awujọ fọwọsowọpọ gbogun ti lasiko yii.