Coronavirus updates: Wo àwọn oníròyìn méje tó kú láàrin ọjọ́ méje ní Nàìjíríà

Oríṣun àwòrán, Facebook
Lootọ ni pe alagbra naa a maa subu, awọn oniroyin lo ṣikeji lẹyin awọn dokita ti wọn si n lewaju lasiko ajakalẹ aarun Covid -19 yii.
Sugbọn o seni laanu pe ọwọja iku ja meje oniroyin Naijiia gba laarin ọjọ meje.
Lati ọjọ meje sẹyin, oniroyin ati akọroyin meje lo ti ku iku Coronavirus ati iku ti ku nise pẹlu aarun naa.
- Ó di gbéré! Arẹwà Ibidunni Ighodalo wọ káà ilẹ̀ lọ nílùú Eko
- Ohun tí a rí nílé Ajimobi rèé lẹ́yìn ìròyìn òfégè pé ó jáde láyé
- Ìwadìí ti bẹ̀rẹ̀ lórí àrá tó sán pa òṣìṣẹ́ FRSC mẹ́ta nípínlẹ̀ Ogun- Ọ̀gá àjọ FRSC
- Gómìnà márùn ún tó fojú winá ìbínú bàbá ìsàlẹ̀ wọ̀n
- Àwọn ohun tuntun tí a mọ̀ nípa ìgbẹ́jọ́ Wòlíì Sotitobire
- Báwó ni òògùn dexamethasone ṣe ń ṣiṣẹ́ lára
Awọn to ku naa ni in:
- Dan Foster ti ile ise radio Cool FM
- Hugo Odiogor ti ile ise Vanguard
- Xiavier Ndayongmong ti Daily Independent
- Nkirukah Udoh ti ile ise AIT
- Naomi Uzor ni ileeṣẹ Vanguard
- Aramide Praise Oikelome Media Project and Independent Newspaper
- Azeez ozi Sanni ayaworan ni The Nation
Nkirukah Udoh
Awọn iṣẹlẹ to n ja kiri awọn ile iṣẹ iroyin yii ko yọ ile iṣẹ oroyin AIT silẹ bi wọn ṣe padanu akọroyin to tun jẹ gbanumọ akaroyin lori mohunmaworn ile iṣẹ naa.
Nkirukan kun nile iwosan aladani kan lẹyin iṣẹ abẹ kan to gbodi
O ti fi igbakan jẹ akọroyin ẹka ilera ati idajọ.
Awọn akọroyin lorilede Naijira n koju oniruuru ipenija gẹgẹ ọkan lara awọn to n lewaju lati koju aarun coronavirus ti wọn si n ṣiṣẹ ni yara ikoroyin jọ lojoojumọ.

Oríṣun àwòrán, Facebook/Dan Foster
Daniel Foster
Dan Foster , Gbajugba sọrọsọrọ lori redio ti gbogbo eeyan mọ si Big Dawg lokiki rẹ kan pe o ku lọjọ kejidinlogun osu yii pe o ti gbkruje lọwọ ẹbọra.
Oniruuru iroyin lo tẹyin rẹ jade ti a ko si ri aridaju iru iku to paa, bi awọn kan se ni aarun coronavirus lo paa, ni awọn miran ni o ti ni arun ẹjẹ riru lo sokun fa rẹ.
Sugbọn iyawo oloogbe naa Lovina salaye fun ile isẹ iroyin Channels pe lọjọru pe ti se ayewo aarun covid -19 ti esi ayẹwo naa si jade lọjọru sugbọn ọsan ọjọ naa lo dagbere f'aye.

Oríṣun àwòrán, Other
Hugo Ifeanyi Odiogor
Lana ode yii niti Odiogor to jẹ ọga agba oniroyin ati alaga nile iṣẹ iroyin Vanguard tẹlẹ ri.
Gẹgẹ bi ẹbi se sọ, Odiogor kulẹyin ọpọlọpọ ọjọ to ti n ṣaisan eyi to si ti mu rinrin ajo lọ si orilede India.
Ooloogbe naa se papoda ni lọsan ana, ọjọ satide ogunjọ, oṣu kẹfa ọdun yii.
Xiavier Ndayongmong
Ko tan sibẹ o, akọroyin nipa iwa ọdaran nile ise iroyin Daily Independent naa dagbere faye lọjọ jimọ, ọjọ kọkandinlogun, oṣu yii.
Aaro ọjọ Jimọ ni wọ sare gbe lọ si ile iwosan kan ni ipinlẹ Ogun ti wọ si daa duro nibẹ, sugbọn ki ilẹ ọjọ naa to su, ọgbẹni Xiavier ti dagbere f'aye.
Gbogbo ẹgb.e awọn akoroyin to niṣe pẹlu ọdaran (CRAN) lo n selede lẹyin akẹgb. Wọn to lọ
Naomi Uzor

Oríṣun àwòrán, Facebook/Naomi Uzor
Naomi Uzor to jẹ akọroyin nipa ọrọ aje nile iṣẹ Vanguard.
Naomi ku laarin osẹ to kọja pẹlu.
Aramide Praise Oikelome
Aramide Praise ku lana, Ogunjọ ọsu kẹfa bakan naa.
Saaju ninu oṣu kẹrin ọdun yii lo n rọ awọ ololufẹ rẹ lju opo iroyin rẹ pe o ti se diẹ ti oun kọ nkan si oju opo naa nitori pe oun padanu aburo ti wọn bi le oun sọwọ aarun coronavirus.
Kos i ẹni ti ọrọ naa ye boya iku coronavirus lo pa Aramide naa abi bẹẹ kọ.
Praise ni oludasilẹ Girls Arise Initiative.
Ọpọ awọn oloufe Aramide lo ti n selede lẹyin rẹ loju opo facebook.
Azeez ozi Sanni
Iku kan ilẹkun de ile iṣẹ iroyin The Nation pẹlu nigba to wọbẹ lọ mu ayaworan wọn lọ Azeez Sanni
Sanni ku lọjọ aje nilu Ibadan.
O ni gba ami ẹyẹ NMMA ni ọdun 2008, 2009, 2010 ati ami ẹyẹ Dame ni lọdun 2009.












