May 29: Akala, Aleshinloye sọ̀rọ̀ lórí ọdún kan Seyi Makinde gẹ́gẹ́bíi gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́

Àkọlé fídíò, May 29: Akala, Aleshinloye sọ̀rọ̀ lórí ọdún kan Seyi Makinde gẹ́gẹ́bíi gómìnà

Ni oni, ọjọ kọkandinlọgbọn oṣu karun un, ọdun 2019 ni wọn bura fun Seyi Makinde gẹgẹ bi gomina ipinlẹ Ọyọ lẹyin to bori ninu ibo ọdun naa.

Ọdun kan lẹyin eyi, BBC News Yoruba gbe ọrọ tọ awọn eekan oloṣelu ni ipinlẹ naa lọ lati mọ ero wọn lori ijafafa iṣẹ iṣejọba ni ipinlẹ Ọyọ.

Abọ ree.