Ṣé òfin kónílé-ó-gbélé lè mú àdínkù bá ìtànkálẹ̀ Coronavirus?
Ọpọlọpọ orilẹ-ede lagbaye lo ti gbe ofin konile-o-gbele kalẹ nitori ajakalẹ arun Coronavirus to n ba aye finra.
Ilẹ Naijiria naa ko gbẹyin ni bo ṣe paṣẹ igbele fun ọsẹ mẹrin.
Ọpọ awọn ọmọ Naijiria lo n sọ pe ko si arun Covid-19 ọhun nilẹ yii, koda, ọpọ n sọ pe ijọba kan fẹ fi ọrọ naa lu owo ilu ni ponpo ni.
Ṣugbọn, ṣe ofin konile-o-gbele lee dẹkun itabnkalẹ arun Coronavirus bi?
Ẹkunrẹrẹ wa ninu fidio yii.