Fayose: Àwòrán ìgbeyàwó ọmọ Fayose táwọn èèyàn ń kẹ́kòó nípa òṣèlú lára rẹ̀

Aworan Fayemi ati Fayose

Oríṣun àwòrán, Twitter/ekitistategov

Àkọlé àwòrán, Tẹrin tayọ lawọn mejeeji fi pade ara wọn nibi igbeyawo ọmọ Fayose
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2

"Ẹ ma gbe ọrọ oloṣelu lori, ṣe ẹ ri Fayemi ati Fayose nibi iyawo ọmọ Fayose abi ẹ ko ri wọn?".

Ọrọ to jọ mọ iru eleyi lo gba ẹnu awọn eeyan kan loju opo ayelujara lẹyin ti aworan awọn oloṣelu mejeeji lu sita nibi ti wọn ti n dọwẹkẹ nibi igbeyawo ọmọ Ayodele Fayose.

Kete ti aworan wọn yii jade sita lawọn kan ti n sọ pe o ṣe afihan pe awọn to n pariwo ija laarin awọn oloṣelu ni lati lọ yẹ ara wọn wo.

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

Skip X post, 2

End of X post, 2

Skip X post, 3

End of X post, 3

Kia lawọn eeyan tun ti wa aworan miran to safihan Minisita feto irina Naijiria Rotimi Amaechi nibi ti oun naa ti n ba Felix Obuah bawọ.

Ṣaaju asiko yii, Amaechi ti wọ Obuah lọ ile ẹjọ lori ẹsun pe o n ba oun lorukọ jẹ ti o si ni ki o san owo itanran ọ́ọ̀dúnrún biliọnu naira nigba naa.

Skip X post, 4
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 4

Arakunrin Ariyo Dare Atoye tilẹ sọ apẹrẹ ni aworan ti Fayose ati Fayemi ya pọ jẹ to si n fi han pe awọn mejeeji yoo yi pada ba ara wọn ṣiṣẹ

Skip X post, 5
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 5

Bi a ko ba tilẹ le sọ ohun to wa ninu ọkan wọn eyi to han ni pe agbo oṣelu ni Naijiria jẹ ibi ti a ti ma n da ọrẹ. Nibẹ naa lawọn miran a si ti ma dọta ti ija wọn ko ni pari.

Pupọ awọn alatilẹyin oloṣelu ni ija wọn kii saba pari ayafi ti awọn ti wọn n gbe lẹyin wọn ba ni o to gẹ.

Bi eeyan ba fi ti wọn ṣe, ko ni fẹrẹẹ si ẹni ti yoo ba ara wọn ṣọrẹ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: