Ìgbeyàwó Fayose: Ìjó Shaku-shaku ni gómìnà fi dárayá

Igbeyawo alarinrin naa waye laarin Tomilọla Fayose ati Arẹwa Ọdunlade lọjọ Satide, ọjọ kejidinlogun, osu kẹjọ ọdun 2018.

Ayọdele Fayose fa Tomilọl, ọmọ rẹ fun ọkọ

Oríṣun àwòrán, @GovAyoFayose

Àkọlé àwòrán, Asọ oyinbo ni gomina wọ lati fa ọmọ rẹ fun ọkọ ni kootu
Gomina Fayose ati aya rẹ, Feyisetan ba tọkọ-taya tuntun ya fọto

Oríṣun àwòrán, @GovAyoFayose

Àkọlé àwòrán, Baba ati iya iyawo ni wọn se bii oloyinbo nibi igbeyawo oloruka ti Tomi Fayose ati Arẹwa Ọdunlade se
Awọn ẹbi ati tọkọ-taya tumtum

Oríṣun àwòrán, @GovAyoFayose

Àkọlé àwòrán, Awọn ẹbi tọkọ-taya tuntun ti parada si asọ ibilẹ wa
Ọkọ iyawo atawọn ọrọ rẹ dọbalẹ niwaju ẹbi iyawo

Oríṣun àwòrán, @GovAyoFayose

Àkọlé àwòrán, So bẹbẹ fẹ, abi o ko bẹbẹ fẹẹ ? Mo bẹbẹ fẹ ni ọkọ iyawo atawọn ọrẹ rẹ n sọ.
Tomilọla Fayose, iyawo tuntun

Oríṣun àwòrán, @GovAyoFayose

Àkọlé àwòrán, Ọmọ to jọ ‘Daddy’ gan ree., oju to n sọrọ
Tọkọ-taya tuntun

Oríṣun àwòrán, @GovAyoFayose

Àkọlé àwòrán, Ololufẹ, maa fẹ ọ titi aye ni tọkọ-taya tuntun n sọ fun ara wọn
Fayose n jo ijo Shaku-shaku

Oríṣun àwòrán, @Emmadex

Àkọlé àwòrán, Ijo shaku-shaku baba iyawo yii, ara ọtọ ni
Fayose n jo ijo Shaku-shaku

Oríṣun àwòrán, @Eletiọfẹ

Àkọlé àwòrán, Haa, o ga ju. Fayose ko kẹrẹ ninu ijo Shaku-shaku
Tomilọla Fayose ati ọkọ rẹ, Arẹwa Ọdunlade

Oríṣun àwòrán, @GovAyoFayose

Àkọlé àwòrán, Iyawo yoo bi isun, yoo bi iwalẹ
Fayose ati iyawo rẹ n se adura fun ọmọ wọn

Oríṣun àwòrán, @sleem_nation

Àkọlé àwòrán, Iya ati baba mo mi lọ, ẹfi adura sin mi o
Iyawo ọsingin joko si aarin iya ati baba rẹ

Oríṣun àwòrán, @Emmadex

Àkọlé àwòrán, Tomilọla, ile ọkọ ya, ki ẹlẹda awọ̀n obi rẹ sin ọ lọ
Ọkọ ati iyawo ya fọtọ pẹlu awọn ọrẹ wọn

Oríṣun àwòrán, @MonteOzAfrica

Àkọlé àwòrán, Iyawo dun lọsingin, ọkọ tun mi gbe