Sanwo Olu: Gomina Ìpínlẹ̀ Eko kọ ‘Your Excellency’ fún ‘Mr Governor’

Gomina ipinlẹ Eko, Babasanwo-Olu

Oríṣun àwòrán, @jidesanwoolu

Àkọlé àwòrán, Sanwo Olu: Wo ohun tí àwon ọmọ Nàìjíríà ń sọ báyìí lórí orúkọ tuntun rẹ̀
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 3

Ọpọlọpọ awọn gomina ti wọn ti jẹ ni ẹkun Iwọ- oorun orilẹ-ede Naijiria lo ti fi igba kan sọ wi pe awọn ko fẹ ki wọn ma a pe wọn pẹlu oye ọlọla julọ 'Your Excellency' ṣaaju orukọ wọn.

Ọpọlọpọ awọn gomina yii maa n lo awọn orukọ naa lati sunmọ ara ilu ati ki ibaṣepọ to danmọran le wa laarin awọn ati awọn ara ilu.

Laarọ oni ni awọn ọmọ Naijiria bẹrọ si ni fun Gomina Ipinlẹ Eko lesi, lẹyin ti oun naa pinnu pe oun ko fẹ 'Your Excellency' mọ lara orukọ oun pe 'Mr Governor' ni oun fẹ ma a jẹ.

Idi ti gomina naa fi lede ni wi pe 'Your Excellency' ti bu iyi kun ipo oun ju iṣẹ to wa nibẹ lọ.

Ati wi pe oun wa lati wa ṣiṣẹ ni ipinlẹ Eko ni, nitori naa ti awọn eniyan ba n pe oun ni 'Mr Governor' yoo ma a ran oun leti idi ti oun fi wa ni ipo ti oun wa lọwọlọwọ.

Lara awọn gomina to ti ko 'Your Excellency' ni iwọ-oorun ile Naijiria ni yii:

  • Gomina tẹlẹri ni ipinlẹ Osun, Rauf Agbesola sọ pe orukọ ti oun fẹ ki awọn eniyan ma a pe oun ni 'Ogbeni' dipo 'Your excellency' nigba to wa lori oye.
  • Bakan naa, Gomina Ipinlẹ Ondo, Arakunrin Oluwarotimi Akeredolu naa ṣọ nigba to de ipo gomina pe oun fẹ ki wọn pe oun ni 'Arakunrin' dipo 'Governor' niwaju orukọ rẹ
  • Gomina Ipinlẹ Ekiti tẹlẹri, Ayodele Fayose ni awọn eniyan maa n pe ni 'Osokomọlẹ' dipo gomina
  • Bola Ahmed Tinubu to jẹ Adari fun ẹgbẹ Oselu APC lorilẹ-ede Naijiria naa jẹ ọkan lara awọn eniyan ti orukọ ti awọn eniyan maa n pe e ni lọpọ igba ko nii ṣe pẹlu ipo to di mu, 'Asiwaju' ni awọn eniyan ma n pe e.
  • Gomina tẹlẹri ni ipinlẹ Ogun, Gbenga Daniel ni awọn eniyan ma n pe ni 'Ogidi ọmọ' lọpọ igba dipo gomina.
Gomina ipinlẹ Eko, Babasanwo-Olu

Oríṣun àwòrán, @DiamondCelebs

Èrò àwọn ọmọ Nàìjíríà ṣọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ lórí Sanwo Olu tó ní kí wọ́n máa pe òun ní "Ọ̀gbẹ́ni Gómìnà"

Lẹyin ti gomina ipinlẹ Eko, Babajide Sanwo-Olu sọrọ loju opo Twitter rẹ pe ki awọn eeyan dẹkun lati maa pe oun ni ọlọlajulọ, ọpọ awọn Naijiria ti n fi erongba wọn lede lori ipinnu yii.

Sanwo-Olu ni oun fẹran ki wọn ma pe oun ni "Ọgbẹni Gomina," dipo Ọlọlajulọ.

Bi awọn kan ṣe ni ipinnu yii dara ni awọn mii n dẹyẹ si gomina ọhun, bẹẹ ni awọn mii n sọ fun un pe ọrọ akọle kọ lokan bayi, bi ko se ki gomina naa ṣe ohun ti awọn ara ilu n fẹ.

Awọn bii Paul Ogwa lori Twitter fara mọ ipinnu yii, wọn gboriyin fun Sanwo Olu pe:

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

Aisha Remi-Adedeji sọ pe ko sohun to kan ẹnikẹni nitori orukọ to wu koowa lo le jẹ́:

Skip X post, 2
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 2

Ni ṣe ni Babajide Adebajo ni tirẹ fi Gomina ọhun ṣe yẹyẹ pe aṣeyọri nla ni orukọ tuntun.

Skip X post, 3
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 3

Àkọlé fídíò, 'Ǹkan tó jẹ́ kí iṣẹ́ ọ̀nà tèmi yàtọ̀ lágbàáyé ni ǹkan tí mò ń lò'

Omonefe Wisdom Omare ni tirẹ sọ pe, yiyi akọle gomina pada ko da nkan nitori ki si anfani ti yoo ṣe fun awọn ara ilu.

Skip X post, 4
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 4

Skip X post, 5

End of X post, 5

Skip X post, 6

End of X post, 6

Salawu Enitan loju opo Facebook ni, Gomina ipinlẹ Ọṣun ana, Rauf Aregbesola ti ṣe iru ohun bayin ri, nitori naa, ko jẹ tuntun.

Skip X post, 7
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 7

Skip X post, 8

End of X post, 8

Skip X post, 9

End of X post, 9

Ẹ wo awọn ohun miran tawọn eeyan tun sọ loju opo Facebook nipa ipinu Gomina yii.

Skip Facebook post

Content is not available

View content on FacebookBBC kò mọ̀ nípa àwọn ohun tí ó wà ní àwọn ojú òpó tí ó wà ní ìta.

End of Facebook post

Àkọlé fídíò, Prepaid Meter: èrò àwọn èèyàn ṣọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ lórí 'sisan owó iná ní Nàìjíríà