Balogun Fire: Àwọn èèyàn tí ìṣẹ̀lẹ̀ náà ṣojú wọn ṣàlàyé ohun tó fa iná lọ́jà Balogun

Àkọlé fídíò, Balogun Fire: Àwọn èèyàn tí ìṣẹ̀lẹ̀ náà ṣojú wọn ṣàlàyé ohun tó fa iná lọ́jà Balogun

Àwọn èèyàn tí ìṣẹ̀lẹ̀ náà ṣojú wọn ṣàlàyé ohun tó fa iná lọ́jà Balogun.

A gbọ pe ọkọ panapana mẹjọ lo de inu ọja naa, ti omi inu gbogbo wọn si tan lori igbesẹ pipa ina naa.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: