David Adiatu oníṣẹ́ ọnà pẹ̀lú ìṣó àti òwú

Àkọlé fídíò, David Adiatu oníṣẹ́ ọnà pẹ̀lú ìṣó àti òwú

Mo fẹ kọ awọn ọdọ sii nipa iṣẹ ọna ìṣó- David

David Adiatu jẹ oniṣẹ ọna to n fi iṣo ati owu da ara to wuu.

Oriṣiriṣi nkan lo maa n fi iṣo ati owu ṣe.

iṣe kafinta ni baba rẹ n ṣe nibi to ti maa n wo baba rẹ.

David gba awọn ọdọ niyanju lati kọ iṣẹ ọwọ kan mọ iwe ti wọn ba n ka nitori pe atẹlẹwọ ẹni kii tan ẹni jẹ.