Premier league: Manchester United jẹ àjẹkún ìyà góòlù méjì lọ́wọ́ Westham United

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Ọwọ iya ba Manchester United ni ile Westham United ni ọjọ Aiku nibi idije Premiership ilẹ Gẹẹsi.
- Man City fi ìkanra na Watford bolẹ̀
- Ọmọ iná làá rán síná, Angel Maria fojú ọlá Real Madrid gbolẹ̀
- Athletico bu omi la ìgara Christiano Ronaldo, ní Madrid
- Ẹgbé agbabóòlù Arsenal ṣe Frankurt báṣubaṣu pèlu ayò mẹta si odo.
- Chelsea sáré kọjá kádàrá, góòlù kan ṣoṣo ní Vanlencia fi lù wọ́n
- Tani yóò gba ife ẹ̀yẹ UEFA Champions League ti saa yi?
Irinajo ti ko lọpẹ ninu ni olukọni iks Manchester United, Ole Gunner Solkjaer ko awọn agbabọọlu rẹ rin lọ si papa iṣire....to jẹ ibuba Westham united nibi ti wọn ti lu wọn ni goolu meji sodo.

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Pẹlu Esi yii, o fihan pe ifẹsẹwọnsẹ meji pere ni Manchester united ṣi bori bayii ni mẹfa ti wọn gba bayii ni saa yii.
Andriy Yarmolenko lo kọkọ gba goolu alakọkọ wọle fun Westham ki Aaron Cresswell to fọba lee nigba ti ifẹsẹwọnsẹ naa wọ iṣẹju kẹrinlelọgọrin.
Lọwọ yii idi olukọni wọn n gbona bayii pẹlu ironu igbesẹ ti awọn alaṣẹ ẹgbẹ agbabọọlu naa lee gbe bi nnkan ko ba ṣe ẹnuure funwọn laipẹ.








