FIFA fòfinde akoọ́nimọ̀ọ́gbá Super Eagles nigbakan ri Samson Siasia

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Gbájúgbàjà kàn nínú èrè ìdárayá Collin Udoh tí fi léde lóju òpó Twitter pé òun ti bá Samson Siasia sọ̀rọ̀ àtí wi pé Siasia ní " mí o mọ ǹkan kan nípa ọ̀rọ̀ tó wà nílẹ̀ yìí.'' Mí ò ṣe ǹkankana láì da bákan náà ní mí ò ti gbà lẹ́tà kankan láti ọ̀dọ̀ FIFA lóri ọ̀rọ̀ yìí"
Collin Udoh fi kún pé ó fi dá òun lójú pé oun yóò jà fiktafita lati wẹ orúkọ oun mọ.
O ní Siasia tún fi kún fún oun pé kò tilẹ̀ sí ẹni tó pé òun láti fi ọ̀rọ̀ wá oun lẹ́nu wò lóri ǹkan to ṣẹlẹ̀ yálà láti sọ tẹ́nu oun tàbí láti ja fún ẹtọ oun, ati pé ìgbà àkọ́kọ́ rèé tí òun náà ń gbọ́ ǹkan tó ṣẹlẹ̀
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 1
Kíní àwọn olúlúfẹ́ bọ́ọ̀lù àti àwọn Nàìjírí[[a ń sọ lóri ìgbésẹ̀ FIFA si Samson Siasia
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 2

End of X post, 3

End of X post, 4
Àjọ FIFA fòfinde Samson Siasia titi lailai
Ajo to n se amojuto ilana ere bọọlu afẹsẹgba lagbaye ti fi ọrọ lede wipe Samson Siasia to jẹ́ akoọ́nimọ̀ọ́gbá Super Eagles tẹ́lẹ̀rí, ti jẹbi ẹsun wipe oun lee gba riba bí ààye rẹ̀ bá yọ, pàápàá jùlọ láti yí èsì ìfẹsẹwọnsẹ bọọlu pàda.
Ajo to ń se amojuto iwa ibajẹ naa ti bẹẹrẹ iwadi lori ọro ọgbeni Siasia láti ọjọ kankanla osu keji ọdun yi.
Eyi to waye leyin iwadi ti ajọ naa se lori bii Ọgbeni Wilson Raj se gbiyanju lati yi esi idije kan pada lati fi ta tẹtẹ.
Iwadi naa ni ajọ FIFA se pelu ifọwọsọwọpọ awọn ẹka miran ninu ajọ bọọlu alafẹsẹgba.
Ninu ipinu wọn, ajọ ti ń se amojuto ilana isẹ ere bọọlu afẹsẹgba naa wipe ọgbeni Siasia jẹbi lodi si ilana ti FIFA gbekale.
Wọn si pasẹ fun lati san owo itanran eyi ti iye rẹ lé diẹ̀ ni miliọnu mejidinlogun naira.