Emir Kano: Ganduje fẹ̀sùn ìkọ́wójẹ kan Emir Sanusi

Oríṣun àwòrán, @Lamidoofficial
Gómìnà ìpínlẹ̀ Kano, Abdullahi Ganduje tí fún Emir Kano, Muhammadu Lamido Sanusi keji ní ìwé wá wi tẹnu rẹ lọ́nìí ọjọ́bọ̀, lóri ẹ̀sùn pé ó ṣe owó mọ́kumọ̀ku.
Ajọ tó ń gbógun ti ìwá àjẹbánu àti gbigbọ́ ẹ̀sun ara ìlú ní ìpínlẹ̀ Kano, ló fẹ̀sún kan Emir tí wọn si dábàá pé kí Emir lo rọ́kun nílé.
- Ọkọ̀ akérò BRT gbiná lórí afárá 3rd Mainland
- Iṣẹ́ Kudirat Abiọla ṣì ń fọhùn síbẹ̀, lẹ́yìn ọdún 23 tó papòdà
- Mi ò gbè lẹ́yìn Naira Mailey fún ìwà ìbàjẹ́- Daddy Showkey
- Ilé alájà mẹ́ta wó pa onímọ̀ ẹ̀rọ́ tó ń kọ́ ọ lọ́wọ́
- Air pollution: Nàìjíríà ni orílẹ̀ède kẹrin tí atẹ́gùn búburú ti ń pa ènìyàn jù làgbáyéé
Olóri oṣisẹ̀ láàfin Emir, Munir Sanusi tó jẹ́ri si gbigba ìwé ẹsùn náà, sọ pe, ìjọba ní ki Emir fesi láàrin wákàti mẹ́rìnlélogun lóri ẹ̀sùn náà.
''A ti gba ìwé ẹ̀sún náà, ìjọba si ti bèèrè fún èsì láàrin wákàtí mẹ́rinlélógún. Awọn ìjòye Emir ń fojú sùnukùn wó ẹ̀sùn náà".








