Iparí UCL: Pápá ìṣiré Kiev gbàlejò Madrid àti Liverpool

ami idanimọ awọ̀n ikọ agbabọọlu Real madric ati Liverpool

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ẹgbẹ agbabọọlu Liverpool ni ẹgbẹ agbabọọlu akọkọ ni ilẹ Gẹẹsi akọkọ ti yoo de ipele aṣekagba

Wo bi gbagede papa iṣire Kiev, ti ifẹsẹwọnsẹ aṣekagba idije Champions league yoo ti waye lọjọ Abamẹta.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

papa isire Kiev

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Real madrid àti Liverpool yóò gbéná kojú ara wọn ní Pápá ìṣiré Kiev láti mọ ọba bọ́ọ̀lú àfẹsẹ̀gbá láàárín àwọn ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lú ní ilẹ̀ Yúróòpú
papa isire kiev

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Real madrid àti Liverpool yóò mọ ọba bọ́ọ̀lú àfẹsẹ̀gbá láàárín àwọn ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lú ní ilẹ̀ Yúróòpú lọjọ abamẹta
Iwaju papa isire Kiev

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Real Madrid ati Liverpool ti kọkọ pade ni ipele aṣekagba ni ọdun 1981
abawọle papa isire kiev

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Real Madrid vs Liverpool: Pápá ìṣiré Kiev ree
Inu papa isire kiev

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Igba marundinlogun ni Real Madrid ti wọ ipele aṣekagba idije yii
Inu papa isire kiev

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Igba meje ni Liverpool ti wọ ipele aṣekagba idije naa
papa isire kiev

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Real Madrid lo tii gba ife ẹyẹ Champions league ju
Inu papa isire Kiev

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Eyi ni igba kẹta laarin ọdun mẹta ti Real madrid yoo maa wọ aṣekagba idije Champions league