Barber ni ọrọ ti a gbe yẹwo loni
A kaakiri lati mọ oye awọn lori ọrọ Yoruba.
A n bi awọn eniyan leere pe ki ni 'barber' ni ede Yoruba?.
- Ẹ wo àwọn gbajúmọ̀ òṣèré tíátà tó jogún eré ṣíṣe lọ́dọ̀ òbí wọn
- Ooni ṣẹ̀ṣẹ̀ fi ẹ̀bùn tuntun ta Olorì Naomi lọ́rẹ tán ní, ìfẹ́ wọn dúró, kò sí ìpínyà- Aàfin Oòdúà
- Coronavirus: Kíni àwọn àmì tuntun tó n fihàn?
- Mọ̀ síi nípa Olorì Abibat Nihinlola Adeyemi tó ti lo ọdún 60 gẹ́gẹ́ bíi olorì láàfin Alaafin Oyo
- Ẹ fura àwọn agbésùmọ̀mi láti Mali fẹ́ wọ ìlú Abuja
BBC Yoruba ko fẹ ki ede Yoruba parun ni aṣe n sṣeto Bawo ni iwọ ṣe gbọ Yoruba to?
Ọpọ pe aerber ni gẹri-gẹri ati fari-fari ni eyi to jẹ Yoruba asiko yii, ṣugbọn Onigbajamọ gangan ni awọn Yoruba n pe Barber.