Adekunle Akindele tó jẹ́ alága PDP ti fèsi sí ẹ̀sùn tí APC fi kan pé PDP ń rán jàǹdùkú kọlu àwọn olóṣèlú APC ní Osun

Àkọlé fídíò, Adekunle Akindele tó jẹ́ alága PDP ti fè[si sí ẹ̀sùn tí APC fi kan pé PDP ń rán jàǹdùkú kọ

Àwọn tọọgi ti APC kó jọ, ti wọn ra ibọn fun ti wọn ko ri owo 'settle' mọ lo n kọlu wọn nsiyi ni Osun kii ṣe awa PDP- Alaga PDP Osun.

Alaga PDP Osun, Adekunle Akindele ba BBC sọro lori ẹsun pé PDP n ran tọọgi lọ kọlu APC lẹyin iburawole gomina tuntun.

Alaga ẹgbẹ oṣelu PDP ti dahun si ẹsun pé PDP n ran janduku lati lọ kọlu awọn oloṣelu inu ẹgbẹ APC ni ipinlẹ Osun.

Alagba Akindele Adekunle to jẹ alaga ẹgbe\oṣelu PDP lo ba BBC yoruba sọrọ lori iṣẹlẹ naa.

O ni alaafia ipinle Osun lo jẹ PDP logun laisi wahala iselu ninu rara.