Debo Adedayo: Agbára wà lọ́wọ́ àwa ọ̀dọ́ lórí ètò ìdìbò 2023- Macaroni

Àkọlé fídíò, Debo Adedayo: Agbára wà lọ́wọ́ àwa ọ̀dọ́ lórí ètò ìdìbò 2023- Macaroni

Èmi kò mọ̀ pé máa di aláwàdà, gbogbo ǹkan tó ń ṣẹlẹ̀ ní Nàìjíríà ló n fún mi ní ìwúrí- Debo Adedayo

Debo Macaroni sọrọ lori awọn iwa ibajẹ to pọ ni Naijiria ati iṣẹ to wa lọwọ awọn ara ilu ati awon oloṣelu.

Alawada yii tun sọrọ fun a\won ọdọ to n japa lọ si ilẹ okeere lasiko yii pe ki wọn ma gbagbe ile rara, ki won si gbe ogo Naijiria ga.

Macaroni

Oríṣun àwòrán, @Macaroni

Ni afikun, Mr Macaroni sọrọ lori iyatọ Daddy Wa ati Debo Adedayo nitori pe oun ko fẹran obinrin rara ati pe oun kii ṣe iṣekuṣe.

O ni pe owo ni oun n wa bayii.

O tun mẹnuba idi ti kii ṣe tẹle awọn akẹgbẹ rẹ lo si ode oloselu rara.