Festus Keyamo: E fìka rẹ́ mi nímú tí Tinubu bá ṣe ìkà fún Kristeni ní 2027

Àkọlé fídíò, Festus Keyamo: E fìka rẹ́ mi nímú tí Tinubu bá ṣe ìkà fún Kristeni ní 2027

Wo ìdí mẹ́rin tí Tinubu ṣe yan 'Muslim- Muslim ticket' - Festus Keyamo

Agbejoro Festus Keyamo to jẹ ọkan pataki lara awọn adari igbimọ ipolongo idibo 2023 fun Bola Ahmed Tinubu to n dije lẹgbẹ oselu All Progressives Congress lo so bẹẹ.

Keyamo ṣalaye idi ti Tinubu fi lọ mu Shetima pe ọgbọn oṣelu lati ri ibo to pọ pupọ ni.

Ati pe Tinubu ko ni ṣe ẹlẹya mẹya iran kankan tabi ko fi ẹsin kan dun ẹsin keji ninu iṣẹjoba re.