Oriogbade: Òwé tí mo pa bú Tíṣà wa ló lé mi kúrò nílé ẹ̀kọ́- Kolapo Odeleye
Ẹ̀yin Obi, ẹ ma sọ ireti nu lori ọmọ akanda ẹda ti ẹ bi yẹn, Olodumare lo mọ ọjọ ọla wọn- Adẹrinpoṣonu Oriogbade
BBC Yoruba wa gbajugbaja adẹrinpoṣonu to n fi owe ṣe awada kan.

Kolapo Odeleye ti ọpọ n pe ni Oriogbade to jẹ akanda ẹda ṣalaye nipa awọn nkan ti oju rẹ ti ri to ko to ẹni ti ọpọ mọ bayii.
O salaye nipa irinajo aye rẹ lati kekere ko to di fọga to n tun taya ọkọ ṣe bayii.
- Báwo ni o ṣe gbọ́ èdè Yorùbá sí?
- Ojútì, ìrẹ́nijẹ àti ìyà àìkàwé nídìí iṣẹ́ tíátà ti ọ̀pọ̀ òṣèré padà sí fásitì
- M-o ti di -born again- lọ́gbà ẹ̀wọ̀n! - Seun Egbegbe bá BBC sọ̀rọ̀
- Kíni ẹ mọ̀ nípa agbègbè Abẹ́sàn án?
- ‘Ọ̀pọ̀ ìyá àwọn “boyfriend” mi ń lé mi, wọ́n ní -Grandma- ni èmi tí wọ́n mú wálé’
- -Ọkọ mi kò ráyè wọ ojú ara mi láti já ìbálé lẹ́yìn oṣù kan ta ṣe ìgbéyàwó-
- N kò fẹ́ ṣiṣẹ́ aṣẹ́wó ló mú mi máa wa ọkọ̀ taxi - Obìnrin tó ń wa ọkọ̀ èrò