ASUU strike UniOsun: Ojọgbọn Adeboye Odunayo Clement: Ìdí ti UniOsun kò se darapọ̀ mọ́ ìyansẹ́lódí ASUU

Àkọlé fídíò, Ojọgbọn Adeboye Odunayo Clement: Ìdí ti UniOsun kò se darapọ̀ mọ́ ìyansẹ́lódí ASUU

Lati ibẹrẹ ni a ti n gba akẹkọọ lati fasiti omiran- Giwa UniOsun

Ni kete ti ile ékọ Giga Fasiti ipinlẹ Osun kede pe aaye wa fun awọn akẹkọọ ti ile ba ti su lataari iyanṣẹlodi ẹgbẹ Oluko Naijiria ni awọn eeyan ti n sọrọ loriiṣirisi.

Eyi lo jẹ ki BBC Yoruba wa Giwa ile ẹkọ giga naa kan lati gbọ ohun to ṣokunfa eyi.

Ojogbon Adeboye Odunayo Clement to jẹ Giwa fasiti naa salaye fun BBC pe kii se tuntun pe UNIOSUN n gba omi lati fasiti miran rara.