How well Sign Board: Ògidì ọmọ Yorùbá, ẹ súnmọ́ ibi kí ẹ wá dán ara wò..

Àkọlé fídíò, Ògidì ọmọ Yorùbá, ẹ súnmọ́ ibi kí ẹ wá dán ara wò..

Kini Yoruba n pe Sign Board?

Ede Yoruba dun o si rẹwa bẹẹ lo kun fun ọgbọn.

Iwo ti oo ba ki n sọ ede Yoruba si ọmọ rẹ ni lati yi pada ki o si fi aṣa ati iṣe omoluwabi kọ ọmọ rẹ.

BBC Yoruba gbe eto yii lati tubọ jé ki awọn eeyan kọ ede Yoruba sii ni.

Ati pe ki ede Yoruba ma se parun ni.

Bawo ni iwọ ṣe gbọ ede Yoruba to?

O ya dan ara wo nipa didahun ibeere oke yii....

Awọn bii Lamidi Isiaka, Oluwafemi Oyedeji, Kayode Omoniyan, Isaac Oladapo, Moshood Halimat, Rauf Adeyemo ati awọn mii gbiyanju ẹ ni ipinle Eko sugbon....