Osun 2022: Òṣì àti àìníṣẹ́ pọ̀ ní Osun, mo ṣetán láti tún ọ̀rọ̀ ajé Osun ṣe- Lasun Yusuf

Àkọlé fídíò, xxx

Láti kékeré ni mó tí ní ẹ̀mí láti sin ìlú mí- Oloye Lasun Yusuf

Oludije ẹgbẹ oṣelu Labour Party ni ipinle Osun ṣalaye ni kikun fun BBC yoruba awọn nkan to ni lọkan lati ṣe fun gbogbo olugbe ipinlẹ Osun.

Oloye Lasun Yusuf sọ nipa iriri rẹ lati ọdun mokandinlogun sẹyin ninu iṣelu Naijiria.

Bakan naa lo tun mẹnuba ohun to fẹ ṣe nipa eto ilera, eto ọrọ aje ati idagbasoke iṣẹ agbẹ.