Ekiti Governorship Election Results: Máàpù tó ṣàlàyé gbogbo èsì ìdìbò Gómìnà ìpínlẹ̀ Ekiti rèé

Gbogbo esi idibo gomina ni ipinlẹ Ekiti ti jade bayii. BBC si ti ṣe maapu ti yoo tọ yin sọna bi ẹ ṣe le ri esi idibo ijọba ibilẹ kọọkan nisalẹ yii.

Bi o se lọ ree pẹlu orukọ awon to n lewaju ati iye ibo ti wọn n gba lawọn ijọba ibilẹ kọọkan ni Ekiti.

Bi ajọ eleto idibo INEC se n kede ibo naa, la n kọ onka iye ibo ti onikaluku ni sinu maapu ti a ṣe agbekalẹ rẹ yii.

Bi ẹ ṣe lee wo esi idibo

Sun atọna (cursor) ori foonu tabi ẹrọ kọmputa rẹ kaakiri ori atẹ to wa nisalẹ yii, yoo ṣafihan ijọba ibilẹ kọọkan ati esi idibo ibẹ.