Fake pastors: BBC Africa Eye díbọ́n bíi ọmọ ìjọ, àṣírí àwọn Pásítọ̀ èké nílẹ̀ yìí tú sí wa lọ́wọ́

Àkọlé fídíò, Fake pastors:

Ayika ati ayida ilẹ Afirika gan ni ibudo ipawowọle wọn.

Amọ bi awọn Pasitọ eke wọnyi ṣe n tan awọn ọmọ ijọ ati alatilẹyin wọn lati jere lara wọn ni ti owo, iyi ati agbara ti di ohun to mu kawọn eeyan ja fun ootọ ẹsin Kristẹni.

Akọroyin ikọ Ọtẹlẹmuyẹ Africa Eye rinrinajo lọ si orilẹede Kenya lati lọ wadii awọn ijọ kan to ti sọ idile ati ọlọdani si ọwọ awọn adari ijọ eke.