Afe Festival IleIfe 2022: Bí ètò ọdún Ajé ṣe lọ ní ìlú Ilé Ifẹ̀ rèé

Àkọlé fídíò, Bíbọ Ajé máaa ń mú kí ènìyàn gbèrú lẹ́nu iṣẹ́ àti okoòwò

Orisa ti a ko ba fi idi ojubọ rẹ han omode kii pẹ́ parun ni awọn agba maa n so nile Yoruba

Oris Aje je ọ̀kan lara awon orisa ilẹ̀ Ooduwa ti wọ́n n bọ ni ilu Ile Ife nipinle Osun ni guusu Iwo oorun Naijiria.Ta ni Ajé tí àwọn ọmọ Yorùbá lágbáyé ń ṣọdún rẹ̀ ní Ile Ife lónìí?

BBC Yoruba ba wọ́n peju pese sibi ti wọ́n ti se ajodun orisa Aje ti odun 2022 ni Ile Ife.

Ki lo de ti Yoruba fi n bọ Orisa Aje nile Ife?

Nibi eto ayeye odun orisa Aje ti odun 2022 ni wọ́n ti salaye kikun lori pataki bibo orisa Aje

Won tun ni pe Bíbọ Ajé máaa ń mú kí ènìyàn gbèrú lẹ́nu iṣẹ́ àti okoòwò

Wo fonran fidio yii ki o si gbadun bi àwọn ará Ilé Ifẹ̀ ṣe bọ ọdún Ajé ti 2022

Koda, won gbamoran pe: Gbogbo orílẹ̀ èdè ló yẹ kó máa bọ Ajé

Ati pataki igbese bibo Aje fun ikoko pe: Tí a bá bi ọmọ tuntun, kò sí kí a má bọ Ajé fún un kó le ní láárí